Home / Àṣà Oòduà / Àwòrán ilé-ìwòsàn Giginju àti irinsé orísirísi ti ilè Kano tí ó jé bílíònù lónà méji àti egbèrin néírà (₦2.8 billion) 

Àwòrán ilé-ìwòsàn Giginju àti irinsé orísirísi ti ilè Kano tí ó jé bílíònù lónà méji àti egbèrin néírà (₦2.8 billion) 

Gómìnà ìjoba ìpínlè Kano ti ra irinsé ńlá fún ilé-ìwòsàn Giginju rè tí ó sèsè kó tán ní ìpínlè Ìjoba náà.

Àwon irinsé náà ni 1.5Telsa Magnet Resonance Imaging, MRI machine, tí ó rà ní owó tí ó tó mílíònù lónà  èédégbèrún, àkókó irú rè tí won ó kókó se sí ilé-ìwòsàn ìjoba ní orílè èdè Nàìjíríà…..

English translation!
Continue after the page break

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...