Home / Àṣà Oòduà / Awure ki Ori gbe ni:

Awure ki Ori gbe ni:

Awure ki Ori gbe ni:
Ori mi gbe mi re Ilu Ilaje
Ibi kedere ni Ela gbemi lo
Ori gbemi re Ilu Ilaya
Ibi kedere ni Ela gbemi lo
Sebi Iregbogbo lo n so ju Aje
Iregbogbo ni se oju Olokun
Ire tomi wa
Ire tomi bo
Oni ile ola
Olo ono ola
Ela Iwori je n ri Aje fii to omo mi Ela Iwori !!
Except by engr Goriola,baba alawo Ile’lawa

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Sanwo olu

Ìpínlẹ̀ Eko ní ìfojúsùn ìpè pàjáwìrì ìsẹ́jú márùn-ún péré

Ìpínlẹ̀ Eko ní ìfojúsùn ìpè pàjáwìrì ìsẹ́jú márùn-ún péré Yínká Àlàbí Ile-iṣẹ Aṣẹ ati Iṣakoso Pajawiri ti Ipinle Eko sọ pe awọn ti setan lati dahun si awọn ipe pajawiri ni ipinlẹ Eko laarin isẹju marun-un pere.Olùdarí Àgbà fún ilé-iṣẹ́ náà, Ọ̀gbẹ́ni Femi Giwa, sọ èyí ní ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò kan pẹ̀lú awọn oniroyin ní ìlú Èkó.Giwa sọ pé àfojúsùn ilé-iṣẹ́ náà ni láti dín àkókò tó wà láàrín ìyè àti ikú kù nípa rírí dájú pé ìdáhùn náà wáyé láàrín ìṣẹ́jú ...