Home / Àṣà Oòduà / Àyàngbàjù! Ògbó-n-tarìgì gbómogbómo, Evans pe ògá olóòpá l’éjó,

Àyàngbàjù! Ògbó-n-tarìgì gbómogbómo, Evans pe ògá olóòpá l’éjó,

**Àti Àwon Méta Míràn Látàrí Àtìmólé Rè Ní Gbogbo Ìgbà.
Ògbó-n-tarìgì gbómogbómo, Chukwudumeme Onuwuamadike tí ìnagije rè ńjé Evans, ó ti pe ògá olóòpá l’éjó, tí orúko rè ńjé Ibrahim Idris àti àwon méta míràn ní ilé ejó gíga ti ìpínlè Èkó látàrí àtìmólé rè ní gbogbo ìgbà.

Àwon tí ó darapò mó ejó náà gégé bi olùdáhùn ni :ilé-isé olóòpá ní orílè èdè Nàìjíríà (Nigerian police force) Komísónà olóòpá (commissioner of police) ìpínlè Èkó àti àwon òngbógunti idigunjalè(special Anti-robbery), Squad, ilé-isé olóòpá Èkó(lagos state police command).

Evans tí owó tè ní inú ilé rè ní Magodo ní Èkó ní ojó kewàá osù kefà (June 10th) ó so wípé àtìmólé òun kò b’ófin mu ó sì so fún àwon olóòpá kí won fi òun sílè.

Nínú pàtàkì ètó omonìyàn ìpèléjó tí won ń ba se látowó àwon olù-gba-ni-n’ímòràn rè, Olukoya Ogungbeje, Evans so fún ilé-ejó kí won so fún àwon olùdálóhùn kí won gbé òun lo sí ilé-ejó ní kíákíá tí ó bá je wípé òfin kan tako òun àti wípé òfin 35(1)(c) (3)(4)(5)(a) (b) àti 36 tí ìwé-òfin ti orílè èdè Nàìjíríà.

Ó so fún ilé-ejó kí ó paáláse àwon olóòpá kí won fi òun sílè bí won kò bá ní èsùn kankan tí ó leè mú òun yojú sílé ejó…..

English Translation !

Continue after the page break bellow.

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo