Home / Àṣà Oòduà / Ayeye Ojoibi Toni: Babami Oloye Olatbosun Oladapo

Ayeye Ojoibi Toni: Babami Oloye Olatbosun Oladapo

Ododun larorogbo
Ododun lari awusa
Ododun lati mo obi lori ate
Ododun ni sapo nruwe
Ododun ni peregun yio
Ododun leo ma bee ninu ola ati Alaafia
Alekun ogbon
Alekun Oye
Alekun IMO
Alekun emi gigun
Alekun Alaafia
Oju asa ki i ribi
Tawodi ki i roran
Leyi toku teo lo laiye oju yin oni ribi
Lagbara Olodumare ao jo peju se teemi ni
Ema farabale last bi HOLY BIBLE ni.
Igba Odun Odun kan nio……. IRE OOO

 

 

King Ogulutu Oro‎

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...