Home / Àṣà Oòduà / BankyW àti Adesua Etomi ti wá di tokotayà báyìí, won sì ti ti fi fi owó sí ìwé èrí ìgbéyàwó won.

BankyW àti Adesua Etomi ti wá di tokotayà báyìí, won sì ti ti fi fi owó sí ìwé èrí ìgbéyàwó won.

     Láìpé ni BankyW àti Adesua Etomi se ìgbéyàwó ìbílè won ní ìlú èkó, àwon tokotayà ti wá t’owó bo ìwé èrí ìgbéyàwó wo, won ti di oko àti aya .

Won ti se ìgbéyàwó alárédè báyìí.
Èyí da àbí kò da .

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

kabiyesi

Èyí wuyì àbí kò wuyì?

Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára