” O le wá fi enu ko ìyàwó lénu báyìí” ni ó ma n dùn jù nínú ìgbéyàwó, tí kò bá rí béè Banky W àti Adesua kò bá má se tó báyìí, won ti fi enu ko ara lénu jù tí àwon àlejò fi so wípé ó ti pòjù, tí won fi pariwo wípé “ó ti tó”.
Èyí le múni ronú o .
Tokotayà tí ó rewà yí kí ara won.
Home / Àṣà Oòduà / Banky W àti Adesua Etomi fi enu ko ara won lénu níbi ayeye ìgbéyàwó alárédè won ní orílè èdè South Africa .
Tagged with: Àṣà Yorùbá
Emi yin a guun oo.. Ase