Home / Àṣà Oòduà / Beverly Naya, Stephanie, Toyin Abraham, Juliet: ta ni ó ró Aso ebí yí jù.

Beverly Naya, Stephanie, Toyin Abraham, Juliet: ta ni ó ró Aso ebí yí jù.

Tani Aso yí dára jù lára rè láàrin àwon arábìnrin arewà méwàá yí. E rò ó e tó mú o, Beverly Naya rewà púpò, Stephanie rè é ojú kò kúrò lára rè, Toyin Abraham dàbí egbin ní tirè, Juliet kò sé fi ojú paré.
Èyin náà e ti è mú kan!.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

kabiyesi

Èyí wuyì àbí kò wuyì?

Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára