Home / Àṣà Oòduà / Davido àti Kiss Daniel nínú o okò ojú òfurufú.

Davido àti Kiss Daniel nínú o okò ojú òfurufú.

Davido àti Kiss Daniel nínú o okò ojú òfurufú.
Gbajúgbajà olórin àti ìlú mòóká olórin tí gbogbo ayé mò sí Wizkid àti Kiss Daniel ya àwòrán papò nínú okò ojú òfurufú aládani. Nse ni ó dàbí eni wípé won fé jo ko orin tí yóò mìlú tìtì papò.
Nse ni ó dàbí eni wípé òré tímó tímó ni won báyìí

About Awo

x

Check Also

kabiyesi

Èyí wuyì àbí kò wuyì?

Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára