Home / Àṣà Oòduà / Diepreye Alamieyeseigha, gomina ipinle Bayelsa nigba kan ri, jade laye leni odun mejilelogota (62)

Diepreye Alamieyeseigha, gomina ipinle Bayelsa nigba kan ri, jade laye leni odun mejilelogota (62)

Diepreye Alamieyeseigha, to je gomina ipinle Bayelsa nigba kan ri, ti jade laye leni odun mejilelogota (62) lana Satide.

Iroyin to te Olayemi Oniroyin lowo fi ye wa wi pe aisan ejeruru lo pa gomina naa.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

kabiyesi

Èyí wuyì àbí kò wuyì?

Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára