Edakun gbogbo ile, e fun mi ni owe to ni ile(house) ninu.
E seun.
Edakun gbogbo ile, e fun mi ni owe to ni ile(house) ninu.
E seun.
Tagged with: Àṣà Yorùbá
A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo
Ile la n wo, ka to somo loruko
Ile Oba to Jo, ewa lo bu si
Ile oloke meje kose fii bomode sere…..
Ile la tin ko eso ro de ?
Ile ni apoti n joko de idi
Ile la tin kesho ro dé