Òpò ni ara ti n yá tí won sì ti fi ojú s’ónà láti wo aso tí Ebuka ma wò ní òtè yí báwo ni ó ti è se ma rí nínú rè ni ìbéèrè àwon ènìyàn, bí ó tilè jé wípé, ó ti da orí èro ayélujára rú látàrí Agbádá nlá tí ó wò lo sí ibi ìgbéyàwó ìbílè won.
Ó kan rora pín àwòrán aso tí ó wò ni àwon olólùfé rè bá bèrè sí ní ma sòrò nítorí wón fé.jù béè lo, sùgbón ó kúlú rewà nínú rè.
Tagged with: Àṣà Yorùbá