E wo ejò tí aládùúgbò mi pa ní ilé àyágbà rè.
O jé kó kúrò ní ilé àyágbé yí.
E wo ejò tí aládùúgbò mi pa ní ilé àyágbà rè.
O jé kó kúrò ní ilé àyágbé yí.
Tagged with: Àṣà Yorùbá
Àwòrán Ogbè Ìwẹ̀yìn wa tòní rè, ẹ jẹ́ kí á rántí àwọn Olùkọ́ tí wọ́n máa ń kó pankẹ́rẹ́ bí ẹni tí ń tẹ̀lé Eégún. Kí lorúkọ Olùkọ́ yín tó máa ń gbé pankẹ́rẹ́ kiri nílé ẹ̀kọ́ Ṣẹ́kọ́ńdírì tí ẹ lọ?
Ebi pa ejo yii oo