Home / Àṣà Oòduà / E wo ohun ti enikan so nipa ile epo Bovas to wa niluu Ibadan

E wo ohun ti enikan so nipa ile epo Bovas to wa niluu Ibadan

Awon arije ni madaru, ika, odaju, ole, wobia, wonbiliki le po ni Naijiria loooto, sugbon awon eniyan rere ko ti tan lawujo wa. Okan ninu won ni alase ile epo Bovas to kale silu Ibadan. Bakan naa ni awon eniyan jeri si wi pe, won ko fi owo kun owo epo won ni awon eka ile ise won to wa kaakiri ile Naijiria.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

kabiyesi

Èyí wuyì àbí kò wuyì?

Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára