Home / Àṣà Oòduà / E wo ohun ti Gomina Fayose n se laaarin oja

E wo ohun ti Gomina Fayose n se laaarin oja


Gomina Ayodele Fayose da moto re duro loja Bisi to wa ni Ipinle Ekiti lati teti si edun okan iya arugbo yii nipa ohun ti won fe ki ijoba o se fun won.  Gomina fara bale lati gbo gbogbo ohun ti iya naa fe so. O si seleri lati se atunse gbogbo ohun ti won on beere lowo ijoba.
E ma je n paro tan yin, mo ti yo ife Foyose bajebaje


About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...