Home / Àṣà Oòduà / E wo ohun ti oyinbo amunisin se lodun 1908

E wo ohun ti oyinbo amunisin se lodun 1908

Awon oyinbo amunisin lati ilu Belgium yegi fun omokunrin, omo odun meje (7) niluu Congo lodun 1908. Ogbeni Femi Fani-Kayode lo se afihan foto yii lori ayelujara. Okunrin naa si tun fi kun un wi pe, ninu awon oyinbo amunisin to daju ju lo, ilu Belgium lakoko, ilu to sikeji ni Jamani.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...