Kí ló n selè báyìí? Se Davido sèsè n bò ni ? Obìnrin ehn ! E wo bí Davido se n wò bí eni tí ó n lo sí àjùlé òrun re .
Òrò kan fun un e jò .
Kí ló n selè báyìí? Se Davido sèsè n bò ni ? Obìnrin ehn ! E wo bí Davido se n wò bí eni tí ó n lo sí àjùlé òrun re .
Òrò kan fun un e jò .
Tagged with: Àṣà Yorùbá
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...