Ojó tí a ti n retí ti pé o! Ebuka pín àwòrán aso tí wò lo sí #BAAD2017 tí ó túmò sí Banky Adesua 2017. Níbi tí ó ti fi ara rè hàn. E wo bí gbajúgbajà yí se ya àwòrán ara rè àti ìyàwó rè níbi ìgbéyàwó pèlú abó oúnje tí won je.
Home / Àṣà Oòduà / Ebuka Obi-Uchenda àti ìyàwó rè, Cynthia Obianodo níbi ayeye ìgbéyàwó alárédè ti Banky W àti Adesua Etomi.
Tagged with: Àṣà Yorùbá