Òdókùnrín tí ó n fi èro ayélujára gbáni, tí ó n se Yahoo yahoo, ni owó ti tè níbi tí ó ti n gbé òkú arábìnrin tí ó pa sí hòtélì lo.
Owó sìkún àwon agbófinró ti te odókùnrin tí ô n gbìyànjú láti gbé òkú arábìnrin aséwó tí ó pa láti fi se òògùn owó lo. Kádúpé wípé owó ti tèé.
