Ọ̀̀rọ̀ mi gbogbo ka sàì yọ́ ikin nínú gẹ̀ẹ̀rẹ̀gẹ̀
Mo sé ní ìwúre ní ojúmọ́ tòní wípé gbogbo ẹ̀sẹ̀ tí a sẹ̀ Ọlọ́run, osó,ajẹ́ àbí ènìyàn bi tiwa ni, tó ń fa ìdíwọ́ kan àbí ìkejì, mo súre fún wa kí Olódùmarè dárí ẹ̀sẹ̀ wa jìnwạ́ gbogbo wa. Àsẹ

Mary Fágbohùn Olórin Afrobeat Seun Kuti ti fi ìrírí ibanuje ọkàn rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà han nígbà tí ọta ibọn kan gúnlẹ̀ lójú fèrèsé yàrá igbalejo rẹ̀. O salaye ibapade to ba ni lẹru naa lori oju-iwe Instagram rẹ, o fi fidio ferese ti ọta ibọn naa bajẹ ati iho re han. Seun, ẹni ti o ṣalaye iyalẹnu, beere iwoye ti aabo ni Amẹrika. Ninu fonran naa, Seun Kuti sọ pe oun wa ninu yara igbalejo, ti oun n sinmi, ...