Home / Àṣà Oòduà / Falz àti 9ice je oúnje alé papò (àwòrán, fídíò).

Falz àti 9ice je oúnje alé papò (àwòrán, fídíò).

Falz ti fi èsì àìgbó ra eni ye hàn láàrin òun àti 9ice nígbà tí òpò rò wípé 9ice ni ó ń báwí nígbà tí ó ń gba àwon olórin ní ìmòràn kí won má fi Orin yin àwon gbájúè mó, nígba tí won ń fi òrò wa lénu wò .

Falz àti 9ice pín àwòrán kan náà, tí àwon méjéèjì jo yà nígbà tí won jo ń jeun sí orí èro ayélujàra (instagram) àwon méjéèjì.

Nígbà tí Falz ya fídío náà ó wípé “E má sì mí gbó “kò sí ìjà láàrin Falz àti 9ice.
9ice ní apá ti rè wípé “ó ti parí “……


English version bellow.

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...