Gómìnà ìpínlè Ekiti Fayose se ìsìn ìdúpé ní gbàgede Lady Jibowu ti ilé ìjoba fún ti ayeye odún ketàdínlógóta ojó ìbí rè. Àwòrán ibi tí ó ti n dì mó ìyàwó rè.
Home / Àṣà Oòduà / Fayose se ayeye odún ketàdínlógóta (57)ojó ìbí rè pèlú ìsìn ìdúpé ní sóòsì pèlú ìyàwó rè.
Tagged with: Àṣà Yorùbá