Arabirin Bamidele Ademola-Olateju lo gbe atejade kan sori ero FACEBOOK re nipa alase Yem-Kem International, Dokita Akintunde Ayeni. O ni gbajue paraku ni maanu naa. Ohun ti arabirin Bamidele tun wa fi kun un ni wi pe, Dokita Akintunde ti wa ninu wahala nla bayii.
Onibara Yem-Kem to n gbe loke okun yii tun so wi pe, owo ti dokita isegun ibile naa ni ati awon alagbara to feyinti lo je ki won ri ina iroyin wahala to ko si naa pamole patapata ti ko fi lu seti awon omo araye.