Home / Àṣà Oòduà / Gbogbo ona loti baje !

Gbogbo ona loti baje !

ona

O dabi ala loju mi ni, mo gbe ero alupupu ti mo sese ra lati ma gbe losi ayika ile Olorun, nitiripe gbogbo ona loti baje, moto ko rorun tabi ya lara lati gbe jade, mo gun ero alupupu naa losi ile Olorun ni owuro yi, lati tun inu ile Olorun se, mo de lati Ile Olorun pada si ile, mo gbe e siwaju ita lati paro aso mi, ki nsi pada sile Olorun, ni mo bawo ita, lodi lau, bi o se ri ero naa mo lati owuro niyen. Ki Olorun gbawa lowo eniti nso ni, ti akomo. Boya Olorun le fun yin ri.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...