Home / Àṣà Oòduà / Gómìnà Nyesom Wike dá òkan lára àwon Konmisôna rè dúró. 

Gómìnà Nyesom Wike dá òkan lára àwon Konmisôna rè dúró. 

Gómìnà ìjoba ìpínlè River, Nyesom Wike ní òwúrò yí dá Konmisôna isé dúró ní ìpínlè rè tí orúko rè ńjé Bathuel Harrison (àwòrán eni tí ó wo jákèètì).  Nínú òrò tí olùrànlówó pàtàkì rè so lórí ìtànná ohun Ìgbéròyìn jáde (Electronic media), Simeon Nwakaudu. Wike so wípé ìdádúró náà esèkesè ni; ó so fún Harrison kí ó gbé ipò fún Akòwé pípé nínú àkóso náà. Kò sí ìdí kan pàtàkì tí won fi lé Konmisônna na níbi isé….

English Translation
Continue after the page break

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

kabiyesi

Èyí wuyì àbí kò wuyì?

Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára