Home / Àṣà Oòduà / Iba akodaaa: Mojuba o !!

Iba akodaaa: Mojuba o !!

iba akodaaa, iba ase daa, iba eyin atun nida, iba eyin alagbara oru, iba eyin alagbara aro, iba eyin t’eledua tun gbe agbara osan le lowo, iba yin o. ORUNMILA iba re, olu ifa, ade ifa, . . .Mojuba o, kiba se e e. ori gbe mi de’bire ayo aiye mi o, Orunmila Timi leyin ki n ribire gbe gba laiye mi o, ASE e e e.

— feeling excited

 

About oodua

One comment

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

seun kuti

Orí kó Seun Kuti yọ kúrò lọ́wọ́ ikú ní yàrá ìgbàlejò US

Mary Fágbohùn Olórin Afrobeat Seun Kuti ti fi ìrírí ibanuje ọkàn rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà han nígbà tí ọta ibọn kan gúnlẹ̀ lójú fèrèsé yàrá igbalejo rẹ̀. O salaye ibapade to ba ni lẹru naa lori oju-iwe Instagram rẹ, o fi fidio ferese ti ọta ibọn naa bajẹ ati iho re han. Seun, ẹni ti o ṣalaye iyalẹnu, beere iwoye ti aabo ni Amẹrika. Ninu fonran naa, Seun Kuti sọ pe oun wa ninu yara igbalejo, ti oun n sinmi, ...