Èrù ti ń ba àwon òpòlopò ènìyàn bóyá àwon ènìyàn kú sí inú ilé tí won ń kó lówó ní òpópónà Stella, Tanke ,Ilorin ,ní ìjoba ìpínlè Kwara tí ó wó ní òsán yí.
English version
Continue after the page break bellow.
Pages: 1 2
Tagged with: Àṣà Yorùbá
Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára