Home / Àṣà Oòduà / Inú àwon olólùfé 2baba dùn púpò nígbà tí won rí olólùfé won ní Glomega music tour tí ó wáyé ní Victoria Island, ní ìlú èkó. 

Inú àwon olólùfé 2baba dùn púpò nígbà tí won rí olólùfé won ní Glomega music tour tí ó wáyé ní Victoria Island, ní ìlú èkó. 

Gbajúgbajà olórin 2baba jé òkan lára àwon tí ó korin ní Glomega tour ní  VI ní ìlú èkó. Ó tún wú àwon ònwòran lórí nígbà tí ó f’akoyo lórí ìtàgé.  Ewo àwòrán bí ó se Ń dá won lárayá n’ísàlè..

Continue after the page break for the English version

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...