Iroyin yajo-yajo to sare wole yii lo n salaye wi pe arabirin Jessica Elvis to je olori egbe awon asewo, oninabi ile Naijiria ti rekoja lo sorun.
Iroyin yajo-yajo to sare wole yii lo n salaye wi pe arabirin Jessica Elvis to je olori egbe awon asewo, oninabi ile Naijiria ti rekoja lo sorun.
Mary Fágbohùn Olórin Afrobeat Seun Kuti ti fi ìrírí ibanuje ọkàn rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà han nígbà tí ọta ibọn kan gúnlẹ̀ lójú fèrèsé yàrá igbalejo rẹ̀. O salaye ibapade to ba ni lẹru naa lori oju-iwe Instagram rẹ, o fi fidio ferese ti ọta ibọn naa bajẹ ati iho re han. Seun, ẹni ti o ṣalaye iyalẹnu, beere iwoye ti aabo ni Amẹrika. Ninu fonran naa, Seun Kuti sọ pe oun wa ninu yara igbalejo, ti oun n sinmi, ...