Home / Àṣà Oòduà / Isé kìí pa ni, ayò ní pa omo ènìyàn

Isé kìí pa ni, ayò ní pa omo ènìyàn

Arábìnrin kan ni aso rè fàya ní enu ìdí látàrí àsejú rè nípa ijó tí ó fé kó mólè dáadáa, kí ó tún owó ijó náà mú láti ilè.
Nínú fídíò tí a rí wò, tí a ti yo àwòrán arábìnrin yí ni a ti ri wípé ó kúkú mò jó súgbón àsejù rè ló mu fa aso ya lójú ìdí, láì wo àwòtélè kankan.

About Awo

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...