Home / Àṣà Oòduà / Iwure Osu Tuntun 01/08/2016

Iwure Osu Tuntun 01/08/2016

E MAA WI TELE MI :
Ire ayo ni temi losu yii.
Ire idunnu ni temi losu yii.
Ire owo ni temi losu yii.
Edumare foro mi se’yanu lose yii.
Igbega ati aseyori ni temi.
Osu yii yoo san mi si rere.
Akoba, adaba ko ni je temi(Ase)

 

Aare Olasunkanmi Alani Agbasaga

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

sibeki

Àjọ EFCC ti ń wá àwọn tó wà nídìí ṣogúndogójì CBEX

Èyí ni àwòrán mẹ́rin nínú àwọn tó wà nídìí ṣogúndogójì CBEX. Àjọ EFCC ti ń wá wọn