Ìyàlénu àti ohun tó mórí wú lójé nígbá tí tè’gbón tà’búrò yí dì mó ara won.
Àwon arewà omodé méjì yí, ni won ti kí a mo rírì ìfé tí èjè máa ni sí ara won.
Omokùnrin kan láti orílè èdè United State ní a rí tí ó n dì mó àbúrò rè obìnrin, nígbà tí ó n se ayeye wípé ó n fi yàrá ìkéèkó kéker kan kalé bó sí Yàrá èkó míràn.
Andrew Tabbs Smith, ìyà àwon omodé wònyí, ni ó pìn àwòrán yí sí orí èro ayélujára.
Tagged with: ÀsàYorùbá