Home / Àṣà Oòduà / John Nani Pa Olúfà Ńlá, John Nani Tí Ó Jé Konmísónà Ní Ìpínlè Delta. 

John Nani Pa Olúfà Ńlá, John Nani Tí Ó Jé Konmísónà Ní Ìpínlè Delta. 

 Konmísónà tí ó ń mójú tó àyíká (commissioner of environment), tí a mò sí Hon. Barr John Nani àti àwon emèwà rè kolu tí won sì pa olúfà ńlá tí ó won òsùwòn tí ó tó mítà lónà mérin ó dín mérin (3.6m) ní Awai nígbà tí won gbìyànjú àti sín kànáà (canal) láti gbógun ti omíyalé..

Continue after the page break for English Version

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

kabiyesi

Èyí wuyì àbí kò wuyì?

Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára