Òkan lára àwon olólùfé Wizkid ni ó ya tàtúù ojú Wizkid àti logo starboy sí èyìn rè…
Home / Àṣà Oòduà / Kàyééfì ò ní yé selè, odóbìnrin kan ni ó ya tàtúù ojú Wizkid àti lógò starboy sí èyìn rè.
Tagged with: Àṣà Yorùbá
Òkan lára àwon olólùfé Wizkid ni ó ya tàtúù ojú Wizkid àti logo starboy sí èyìn rè…
Tagged with: Àṣà Yorùbá
A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo