Home / Àṣà Oòduà / Kcee tú àsírí pé òhun ni olórin àkókò ní ìròlé èdè Nàìjíríà tí ó kókó lo okò bògìnì tí a mò sí Rolls-Royce phantom nínú fídío Orin rè. 

Kcee tú àsírí pé òhun ni olórin àkókò ní ìròlé èdè Nàìjíríà tí ó kókó lo okò bògìnì tí a mò sí Rolls-Royce phantom nínú fídío Orin rè. 

Gbajúgbajà olórin,  Kcee o ní ìràwò márùn-ùn. Nínú Orin tí ó ti se jé kí á rí àsírí rè gégé bí àsáájú tí ó kókó lo okò bògìnì “Rolls-Royce   ní ilé-isé olórin ní orílè èdè Nàìjíríà. Òun ni ó jé òsèré àkókò tí ó kókó lo irú rè kan ní ibi fídío Orin rè, Shokori Bobo.
Àrídájú yí wá nígbà tí a  fi òrò wa lénu wò ; ó so wípé; “Èmi ni òsèré àkókò ní orílè èdè Nàìjíríà láti lo Roll-Royce phantom nínú fídío Orin mi.
E lo wo Shokori Bobo. Ní àkókó yan ni èmi pèlú Phresh se fídío náà. Enikéni kò tí lo Roll-Royce nígbà yan. Ókéré nínú gbogbo èyí tí mo le rántí, òpòlopò ló ti ń wí tenu won nípa rè.Tí àwon kan so wípé D’banj ko Mr. Endowed Remix pèlú oko bògìnì yí nígbà tí ó wà pèlú Mo’Hits.
 
Kí l’erò, nítòótó? Tani àsáájú tí ó kókó lo okò bògìnì tí a mò sí Rolls-Royce ni ibi fídío Orin rè ní orílè èdè Nàìjíríà? Kcee tí ó gbé Orin rè Shokori Bobo jáde ní 2008 àbi D’banj nínú Orin rè Mr. Endowed remix ni 2011? Ó hàn gàdàgbà lóòtó? Sùgbón Ná.
Ejé kí á gba èrò yín nípa òrò náà…


Continue after the page break for English translation.

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

kabiyesi

Èyí wuyì àbí kò wuyì?

Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára