Kì í kú se wípé olórun d’àwa l’ájá béè kò dáwa l’éranko bí kò se wípé ó dáwa láláwò dúdú, ó sì dá àwon kan pupa. Sùgbón kò fi enìkan se erú enìkan.

Tagged with: Àṣà Yorùbá
Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára