Inu fiimu wo ni foto yii ti jade?
Inu fiimu wo ni foto yii ti jade?
Tagged with: Àṣà Yorùbá
A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo
Saworo ide
Agogo eewo. Baba Lere Paimo, Dr Larinde Akinleye ati Abiola Atanda….Madam Kofo.
Chief Lere Paimo, Alabi Yellow ati Biola Atanda aka Madam Kofo. Ninu fimu saworo ide.
Lere Paimo,Madam Kofo,Oloogbe Larinde Akinleye……nini fIimu Agogo Eewo,eyi ti ile ise Mainframe Production gbe sita
Agogo Eewo