Home / Àṣà Oòduà / Kukute ti darapo mo awon alakatakiti esin Islam

Kukute ti darapo mo awon alakatakiti esin Islam


Okunrin arara yii ni won ti ri pelu awon alakatakiti esin Islam, Jabhat Al-Nusra niluu Syria. Jabhat Al-Nusra yii ni o ni ajosepo pelu iko AlQaeda eleyii ti Osama Bin Laden wa lara awon oludasile re ko to di wi pe bajinatu Obama ba latari ori.  Ohun iyalenu ni wi pe ibon sakabula ti won gbe fun okunrin arara yii gun ju lo, sibesibe, oun naa ni dandan ni ki oun naa jagun jiyaadi.

 

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*