Home / Àṣà Oòduà / Lori Eto Tonii: Kini nje Ela ?

Lori Eto Tonii: Kini nje Ela ?

* Kin ni nje ELA ? Abi Taani ‪#ELA‬ je gan-an ?
* Nje ‪‎ESIN‬ ati ‪#ASA‬ Yoruba tako ara won
bi ?
* Bawo ni ‪# Ela_boru‬ , ‪ Ela Boye‬ ,
‪  Ela bo sise‬ se je Ede ikini fun awon ‪  Babaalawo‬ ?

E yin redio(radio) yin si ikanni ‪#‎UNIQ_103‬
.1FM, Ilesa, ni dede agogo mewaa abo
owuro (10:30am) oni; fun akotun eto
‪#‎ISESE_OMO_OODUA‬ Rere.

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...