Home / Àṣà Oòduà / Má Jẹ Àkàrà Ọ̀ràn Sími Lọ́rùn

Má Jẹ Àkàrà Ọ̀ràn Sími Lọ́rùn

Sponsored by Àsà Yorùbá

I pray this morning for everyone of that we shall never receive a visitors that we put us into trouble or police Affairs by the special grace of God

Eu rezo esta manhã para todos que nunca receberemos visitantes que nos colocam em problemas ou caso da polícia pela graça especial de Deus

Awóyemí Ọlọ́run wà 1
Oní ìgbàgbọ́ to ba wa níbí ko sọ wípé

Èmi ò ní gba àlejò ọ̀ràn tọmọ tọmọ tẹbí tará mi

About ayangalu

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo