Home / Àṣà Oòduà / “Mo ti rí eni náà” Burna Boy pín àwòrán tí ó rewà pèlú arábìnrin arewà kan.

“Mo ti rí eni náà” Burna Boy pín àwòrán tí ó rewà pèlú arábìnrin arewà kan.

“Mo ti rí eni náà” Burna Boy pín àwòrán tí ó rewà pèlú arábìnrin arewà kan.


Gbajúgbajà àti ogbóntarìgì olórin tí a mò sí Burna Boy nse ni ó dàbí eni wípé ó ti rí àyànfé, ó pín àwòrán tí won dì mó ara won, bí ó tilè jé wípé a kò mo arábìnrin arewà yí.
Ó pín àwòrán náà pèlú òrò tí ó ya ni lénu.
E wo àwòrán náà.

About Awo

x

Check Also

kabiyesi

Èyí wuyì àbí kò wuyì?

Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára