Home / Àṣà Oòduà / Musiliu Obanikoro ti fi tòwòtòwò darapò mó egbé APC.

Musiliu Obanikoro ti fi tòwòtòwò darapò mó egbé APC.

Olóyè Musiliu Obanikoro ti fi tòwòtòwò fi egbé alásìá, PDP (People Democratic Party)sílè lo dí egbé onígbálè APC (All Progressive Congress).
Ìròyìn jé kí á mò wípé ìgbésè Obanikoro lo sí egbé tuntun ti bèrè láti bi osù mélòó séyìn sùgbón won sèsè gbà á láyè gégé bi omo egbé ni .
Won sì ti ki káàbò gégé bi omo egbé APC (All Progressive Congress).

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

kabiyesi

Èyí wuyì àbí kò wuyì?

Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára