À béè rí nkan, e ri bí won se se jómúrégí papò! Won bá ara won mu gan ni…
Home / Àṣà Oòduà / Nínú agbami ifè ni won wà, gbajúmò òsèré Mode Funmi Martins àti oko rè Afeez Owo fi ìfé won hàn.
Tagged with: Àṣà Yorùbá
À béè rí nkan, e ri bí won se se jómúrégí papò! Won bá ara won mu gan ni…
Tagged with: Àṣà Yorùbá
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...