Home / Àṣà Oòduà / O di gbere! Abubarka Audu wole sun

O di gbere! Abubarka Audu wole sun

O ku die ko je gomina niku mu lo. Igba ti okiki re bere si ni i kan, lo wole sun.

Ojo ti idile re i ba fo fayo, ni won bo sinu ibanuje nla.

Ile aye asan, ile aye omulemofo.

Bawo ni ko ba se dun to kiku gbowo? Sebi opolopo owo dollar ni won o ba ko le iku lowo.

Sugbon iku o gbowo, Omooba Abubarka Audu niku mu lo.

Rere run! Nnkan yan-an!

Adura kan ni mo fe gba fun gbogbo eyin ololufe Olayemi Oniroyin pata: ojo ayo yin, ko ni pada dibanuje lagbara Olorun Oba oke. Amin.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Awon foto lati ibi eto isinku Abubarka Audu nipinle Kogi

Won sin Abubakar Audu lonii ni ilu re, Ogbonicha to wa ni ijoba ibile Ofu ni ipinle Kogi.