Home / Àṣà Oòduà / Obi ni n bi arun

Obi ni n bi arun

Aboru
Aboye
Abosise..
Ifa niiiiii

Obi ni n biku
Obi ni n bi arun
Obi ni n bi ofo
Obi ni n bi gbogbo ibi.
Olodumare abawa fi obi biku, bi arun, bi ofo, bi gbogbo ajogun ibi aye wa o.
Ase edumare.

Sponsored by Asa Oodua

Cola nut helps to avoid death
Cola nut helps to avoid disease
Cola nut helps to avoid lost
Cola nut helps to avoid all kind of problems.
I pray Olodumare will use Cola to take away all the problems in our life.
Ase edumare.

About ayangalu

x

Check Also

Bàbá Olóyè Ebenezer Obey Fabiyi

Bàbá Olóyè Ebenezer Obey Fabiyi kú ayẹyẹ oríkádún wọn

Ẹ jẹ́ kí á jọ kí GBajúmọ̀ Akọrin Jùjú nílẹ̀ yìí, Olóyè Ebenezer Obey Fabiyi kú ayẹyẹ oríkádún wọn ti ọdún kẹtàlélọ́gọ́rin (83) tó kò lónìí. Kí Olódùmarè ó fi àlàáfíà ṣe ẹ̀bùn Ogbó fún Bàbá