Home / Àṣà Oòduà / Òdóbìnrin ni ó ya àwòrán orúko Runtown gangan sí ìdí rè.

Òdóbìnrin ni ó ya àwòrán orúko Runtown gangan sí ìdí rè.

    Níbáyìí, ojú wo ni òrékùnrin rè ma fi wò ó tí ó bá rí ìdí òdóbìnrin yí?.

Àwòrán tí ó ti gba èro ayélujára kan ni ti obìnrin tí ó ko orúko Runtown gangan sí ìdí rè.

Olórin ìgbàlódé kan tí ó n jé Runtown tí orúko rè gangan n jé (Douglas Jack Agu ) ní ègbé òdóbìnrin yí ni àwòrán okùnrin yí n hàn.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...