Home / Àṣà Oòduà / Odunlade Adekola ti parí ìdánwò è ní UNILAG.

Odunlade Adekola ti parí ìdánwò è ní UNILAG.

   Gégé bí ó ti pin sí orí èro ayélujára (Instagram).

” Nígbà tí o bá parí ìdánwò, tí o wá n padá li sí ilé , tí o wá kó sínú súnkere fàkere oko, wà sà ya àwòrán, mo kí ara mi àti gbogbo akékòó ilé -èkó UNILAG wípé àseyorí nínú ìdánwò wa.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

kabiyesi

Èyí wuyì àbí kò wuyì?

Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára