Home / Àṣà Oòduà / Ogbe Ni Alabo Kan yin ibon pa Orere Ni ilu Enugu

Ogbe Ni Alabo Kan yin ibon pa Orere Ni ilu Enugu

Oṣiṣẹ alabo kan ti orukore unje ogbeni Chidi Onyenekwu, padanu emi e lala iro tele, nipase asise ti ikan ninu awon ti won jo unsise abo se,
Ni ibamu si Ọgbẹni Ugonna Chiji Achuko ti, afi oro wa nenu wo, so wipe, eni ti isele na ti owo re sele, gbe oju ibon re soke lati yan awon ota inu ibon na sonu, sugbon ti o gbagbe lati da oko ibon na pada nigba ti o ko ojure wale,  nipase eyin ti o si ko oju ibon na si aya ogbeni ti o fi aye sile yi, ti o si yin ibon na mon laya, eyi ti ofa iku a iro tele fun ogbeni Chidi.
Iṣẹlẹ yi ipe fun ikẹkọ ti o ye koro fun awon alabo wa ni gbakugba ti won ba gbe ibon lowo lati ma sora se.

 

English Version
Continue reading after the page break

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...