Home / Àṣà Oòduà / Ogulutu Oro Toni

Ogulutu Oro Toni

Igbiyanju loma ngbeni de ipo ola
Igbiyanju loma njeki kadara o se
# wo
Oremi masinmi igbiyanju oo ki o le dele ileri
Majeki isoro kisoro kopa okanre da Lori ipinu ayo re
Tepa mose re loni
Ki osi mo wo owolowo juen yio dara fun oooo.
IRE OO OOOO

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...