Wo binu ba nbio masoro, tinu re basi ndun mase ile ri, fi eniyan buburu sile saye re.
# wo Mase mura lati gbija arare fija le f’OLOHUN,ohun nikan loba elesan…..
Ire oo
Wo binu ba nbio masoro, tinu re basi ndun mase ile ri, fi eniyan buburu sile saye re.
# wo Mase mura lati gbija arare fija le f’OLOHUN,ohun nikan loba elesan…..
Ire oo
Tagged with: Àṣà Yorùbá
A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo