Ile to mo wa loni, ka ma subu ka ma feyin owo danu,toripe ojumo ire ni, ka ma ko elenini ka ma ko agbako toripe ojumo ire ni,ori owo Lori wa loni, ESE aje lese wa lonj aji lowuro ati ba eleda soro wipe koni San wa so rere. Oti ribe koyi pada Ase

Tagged with: Àṣà Yorùbá
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...